Oko
Ilẹ̀ fún ohun ọlgbìn From Wikipedia, the free encyclopedia
Remove ads
Oko jẹ́ ilẹ̀ tí a yà sọ́tọ̀ fún ohun ọ̀gbìn tí ó lè ń pèsè ohun jíjẹ tàbí oúnjẹ fún àgbẹ̀ àti ẹbí rẹ̀.[1]Oko lè jẹ́ ilẹ̀ tí a fi ń gbin àwọn ohun jíjẹ afáralókun bíi iṣu, ẹ̀gẹ́, àgbàdo, ọ̀dùnkún àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ. A sì tún lè fi oko ṣe ohun ọ̀gbìn ewébẹ̀ bíi: ẹ̀fọ́, èso. Ó sì tún lè jẹ́ oko tí a fi ń ṣe ohun ọ̀sìn abẹ̀mí bíi: ẹja ẹran sínsìn, adìẹ sínsìn, ehoro sínsìn àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ. A lè fi ibùgbé wa ṣe oko tàbí kí a fi oko wa ṣe ibùgbé, bákan náà ni ilẹ̀ oko lè jẹ́ ti gbogbo ẹbí tàbí kí ó jẹ́ ti àdáni. [2]


Remove ads
Àwọn ìtọ́kasí
Wikiwand - on
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Remove ads