Patrick Manning

From Wikipedia, the free encyclopedia

Patrick Manning
Remove ads

Patrick Augustus Mervyn Manning (ojoibi 17 August 1946) je oloselu ati Alakoso Agba kerin ati ikefa orile-ede Trinidad ati Tobago tele, bakanna tele ohun lo je olori egbe oselu People's National Movement (PNM)[1]. O di Alakoaso Agba lati 17 December 1991 de 9 November 1995 ati lati 24 December 2001 titi di 26 May 2010. O tun je Olori Olodi lati 1986 de 1990 ati from 1995 to 2001. Ohun nlo je olori egbe oloselu PNM lati 1987 de 2010. O gba eko bi aseorooriile, Manning ti je bi Omo Ileasofin fun agbegbe Ilaorun San Fernando lati 1971, loni ohun ni omo Ile awon Asoju to wa nibe pejulo.[2]

Quick facts The HonourablePatrick Manning MP, 4th & 6th Prime Minister of Trinidad and Tobago ...


Remove ads

Itokasi

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads