Peruzzi
Nàìjíríà olórin From Wikipedia, the free encyclopedia
Remove ads
Tobechukwu Victor Okoh (tí a bí ní ọjọ́ karùn-ún, oṣù kejìlá, ọdún 1989), tí orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ ń jẹ́ Peruzzi, jẹ́ olórin àti akọ-orin sílẹ̀ ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ọmọ ọdún méje ló wà nígbà tí ó bẹ̀rẹ̀ sí ní kọrin.[1] Ó di gbajúgbajà òṣèré nígbà tí 2face Idibia ṣe àfihàn rẹ̀ nínú orin 'Amaka' tó kọ.[2]
Remove ads
Iṣẹ́ rẹ̀
Ó ni ìyàwòran ilé-ìṣeré àkókọ rẹ ní ọdún 2007 àti pé láti ìgbà náà ,ó ti ñ ṣe gbigbasilẹ orin. Peruzzi lọ sí ilé-ìwé alákọbẹrẹ Lerato ní Egbédá, Ipinle Eko, Nigeria ó sì gba Iwe-ẹri Ilọkuro Ile-iwe akọkọ rẹ. Lẹhin ipari ẹkọ ile-iwe alakọbẹrẹ rẹ, Peruzzi tẹsiwaju si Command Secondary School ni Ikeja, Ipinle Eko, Nigeria ó sì gba ìwé-èrí Ilé-iwé gíga ti Iwọ-oorun Afirika ni ọdun 2007. Peruzzi bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ orin kíkọ rẹ̀ pẹ̀lú Golden Boy Records ní ọdún 2016, kí Davido Music World tó gbà á wọlé sínú ẹgbẹ́ wọn ní ọdún 2018. Orin tí Peruzzi dá kọ ní ọdún 2018, tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ Majesty, ní ó fi ṣe àfihàn Cee-c tó jẹ́ olúborí ètò 'Big Brother Naija' ti ọdún 2018 nínú fídíò rẹ̀. Kí ó tó kọrin àdákọ rẹ̀, níṣe ni àwọn ènìyàn ń sọ pé orin-olórin ló fi ń yan, tó sì fi ń hàn.[3][4][5] Ó hàn nínú orin 2face Idibia kan tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ "Amaka".[6][7][8] Perruzzi tan mọ́ ìyàwó àfẹ́sọ́nà Davido tí orúkọ rẹ ń jẹ́ Chioma.
Remove ads
Àtòjọ orin rẹ̀
Orin àdákọ
Remove ads
Àwo-orin
Àwọn àmì-eye tó ti gbà
Remove ads
Àwọn Ìtọ́kasí
Wikiwand - on
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Remove ads