Filipínì

From Wikipedia, the free encyclopedia

Filipínì
Remove ads

Filipínì tabi Àwọn Filipini (Àdàkọ:Lang-fil Àdàkọ:IPA-tl), fun onibise bi orile-ede Olominira ile awon Filipini (Àdàkọ:Lang-fil), je orile-ede kan ni Guusuilaorun Asia ni apaiwoorun Okun Pasifiki. Si ariwa re niwaju Luzon Strait ni Taiwan wa. Ni iwoorun niwaju Omi Okun Guusu Saina ni Vietnam wa. Omi Okun Sulu ni guusuiwoorun wa larin re ati erekusu Borneo, be si ni ni guusu ni Omi Okun Selebes pinniya kuro si awon erekusu Indonesia miran. O bode mo Omi Okun Filipini ni ilaorun. Oluilu re wa ni Manila.

Quick facts Orílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ Àwọn Filipínì Republic of the Philippines Republika ng Pilipinas, Olùìlú ...


Remove ads

Itokasi

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads