Queen Nwokoye
From Wikipedia, the free encyclopedia
Remove ads
Queen Nwokoye (tí a bí ní 11 Oṣù Kẹẹ̀jọ, Ọdún 1982) jẹ́ òṣèrébìnrin ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[2][3] Ó gbajúmọ̀ fún kíkó ipa olú-ẹ̀dá-ìtàn nínu eré kan ti ọdún 2014 tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Chetanna, èyítí ó ṣokùn fa tí wọ́n fi yàán fún àmì-ẹ̀yẹ "Òṣèrébìnrin tó dára jùlọ" níbi ayẹyẹ Africa Movie Academy Awards .[4]
Remove ads
Ìbẹ̀rẹ̀ ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀
Ìpínlẹ̀ Èkó ni wọ́n bí Nwokoye sí, ṣùgbọ́n àwọn òbí rẹ̀ wá láti Ìpínlẹ̀ Anámbra.[5] Ó bẹ̀rẹ̀ ẹ̀kọ́ rẹ̀ ní ilé-ìwé alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ Air Force Primary School. Ó sì tún parí ẹ̀kọ́ girama rẹ̀ ní Queen's College ti ìlú Enúgu ṣááju kí ó tó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ gíga Yunifásítì Nnamdi Azikiwe ní ìlú Awka, Ìpínlẹ̀ Anámbra níbi tí ó ti kẹ́kọ̀ọ́ ìmọ̀ àwùjọ. Ó dàgbà pẹ̀lú ìpinnu láti di amòfin.[6]
Iṣẹ́ ìṣe rẹ̀
Láti ìgbà tí ó ti ṣe àkọ́kọ́ eré rẹ̀ ní ọdún 2004, Nwokoye ti ṣe bẹ́ẹ̀ kópa nínu ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn fíìmù ti Nàìjíríà, tó sì tún gba aẁọn àmì-ẹ̀yẹ lóríṣiríṣi[7][8]
Àtòjọ àwọn àṣàyàn eré rẹ̀
- Nna Men (2004)
- His Majesty (2004)
- The Girl is Mine (2004)
- Security Risk (2004)
- Save The Baby (2005)
- Back Drop (2005)
- Speak The Word (2006)
- My Girlfriend (2006)
- Last Kobo (2006)
- Lady of Faith (2006)
- Disco Dance (2006)
- Clash of Interest (2006)
- The Last Supper (2007)
- When You Are Mine (2007)
- The Cabals (2007)
- Show Me Heaven (2007)
- Short of Time (2007)
- Sand in My Shoes (2007)
- Powerful Civilian (2007)
- Old Cargos (2007)
- My Everlasting Love (2007)
- Confidential Romance (2007)
- The Evil Queen (2008)
- Temple of Justice (2008)
- Onoja (2008)
- Heart of a Slave (2008)
- Female Lion (2008)
- Angelic Bride (2008)
- Prince of The Niger (2009)
- Personal Desire (2009)
- League of Gentlemen (2009)
- Last Mogul of the League (2009)
- Jealous Friend (2009)
- Makers of Justice (2010)
- Mirror of Life (2011)
- End of Mirror of Life (2011)
- Chetanna (2014)
- Nkwocha (2012)
- Ekwonga (2013)
- Ada Mbano (2014)
- Agaracha (2016)[9]
- New Educated Housewife (2017)
- Blind Bartimus (2015)
- Coffin Buburu (2016
- Iyawo Ti a Yan
Àwọn ìyẹ̀sí rẹ̀
Remove ads
Ọ̀rọ̀ ayẹ́ rẹ̀
Nwokoye ti ṣe ìgbeyàwó pẹ̀lú Ọ̀gbẹ́ni Uzoma, ó sì ti bí àwọn ọmọ ìbejì okùnrin[15] àti ọmọbìnrin kan. [16]
Àwọn ìtọ́kasí
Àwọn ìtakùn Ìjásóde
Wikiwand - on
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Remove ads