Quincy Jones

Òṣèré Ọmọ Orílẹ̀-èdè America (1933–2024) From Wikipedia, the free encyclopedia

Quincy Jones
Remove ads

Quincy Delight Jones, Jr. ( March 14, 1933 -Oṣù Kọkànlá 3 ,2024) je ara ile Amerika to je alakoso orin, atokun awo orin, eleto orin, alasopo orin filmu, atokun telifisan, ati afonfere. Larin adota odun to fi sise ninu ise faaji, Jones gba idaloruko fun Ebun Grammy ni igba 79 to je eni akoko to gba eyi,[1] 27 awon Ebun Grammy,[1] ti Ebun Akikanju Grammy ni 1991 je ikan ninu won. O gbajumo gege bi atokun awo orin Thriller, ti Michael Jackson gbe jade ni 1982, eyi to ta iye to je 110 legbegberun kakiriaye,[2] ati atokun ati alakoso orin ore anu “We Are the World”.

Quick facts Background information, Orúkọ àbísọ ...
Thumb
Jones in 2004 at the World Economic Forum in Davos



Remove ads

Itokasi

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads