Quinton Aaron
Òṣèré Ọmọ Orílẹ̀-èdè America From Wikipedia, the free encyclopedia
Remove ads
Quinton Aaron (tí a bí ní ọjọ́ karùn-úndínlógún oṣù kẹjọ, ọdún 1984)[1][2][3] jẹ́ òṣèré orílẹ̀-èdè American actor. Ó ṣe fíìmù àkọ́kọ́ rẹ̀ nínú eré Michel Gondry tó ń jẹ́ Be Kind Rewind. Ẹ̀dá-ìtàn tó kọ́kọ́ ṣe ni ibi tí ó ti ṣe Michael Oher nínú fíìmù kan ní ọdún 2009 tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́The Blind Side.[4][5][6]
Remove ads
Ìbèrẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀
A bí Aaron sí The Bronx, New York City, àmọ́ ó kó lọ sí Augusta, Georgia lẹ́yìn tó parí ilé-ìwé alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ rẹ̀.[7]
Àtòjọ fíìmù àgbéléwò rẹ̀
Fíìmù
Orí amóhùn-máwòrán
Àwọn fọ́nrán olórin
Remove ads
Àwọn ìtọ́kasí
Wikiwand - on
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Remove ads