Raphael Saadiq
From Wikipedia, the free encyclopedia
Remove ads
Raphael Saadiq ( /səˈdiːk/; orúkọ àbísọ Charles Ray Wiggins; May 14, 1966) ni akọrin, akọ̀wé-orin, onílù-orin, àti olóòtú àwo-orin ará Amẹ́ríkà. Ó gbajúmọ̀ bíi ọ̀kan nínú ọmọ ẹgbẹ́ olọ́rin Tony! Toni! Toné!. Ó ti ṣe olóòtú orin fún àwọn akọrin míràn bíi Joss Stone, D'Angelo, TLC, En Vogue, Kelis, Mary J. Blige, Ledisi, Whitney Houston, Solange Knowles àti John Legend.
Remove ads
Ìtọ́kasí
Wikiwand - on
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Remove ads