Recep Tayyip Erdoğan

From Wikipedia, the free encyclopedia

Recep Tayyip Erdoğan
Remove ads

Recep Tayyip Erdoğa (tí a bí ní ọjọ́ kẹrindínlógbọ̀n oṣù kejì ọdun 1954) jẹ́ olóṣèlú àti Ààrẹ orílè-èdè Turki láti ọdun 2014. Òun ni mínísítà àgbà orílè-èdè Turki láàrin ọdun 2003 sí 2014 àti mayor instabul láàrin ọdun 1994 sí 1998. Ní ọdun 1998, wọ́n yọ́ kúrò ní ipò Mayor Instabul wọ́n sì ran lọ sí ẹ̀wọ̀n fún oṣù mẹ́rin lórí ẹ̀sùn pé ó ń fa wàhálà ẹ̀sìn. [2][3]

Quick facts Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Turkey, Alákóso Àgbà ...
Remove ads

Àwọn Ìtọ́kasí

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads