Rómù Olómìnira

From Wikipedia, the free encyclopedia

Rómù Olómìnira
Remove ads

Orílẹ̀-èdè Olómìnira àwọn ará Rómù (Latini: Res publica Romanorum) ni a n pe igba itan Romu ti awon ara Romu le oba ikeyin won kuro lori ite lati sepilese oselu. Igba oselu tabi igba olominira bere pelu iwolulo oba tokeyin ara Etruski, eyun Tarkuinu Onigberaga (Tarquinius Superbus) ni 509 kJ o si dopin pelu ibori Oktabiani lori Marku Antoni ni Ija Aktiomu ni 31 kJ.

Quick facts



Remove ads

Itokasi

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads