Rukky Sanda
From Wikipedia, the free encyclopedia
Remove ads
Rukayat Akinsanya (bíi ni kẹtàlélógún oṣù kẹjọ ọdún 1984[1]) tí orúkọ inagi rẹ̀ jẹ́ Rukky Sanda jẹ́ òṣèré àti adarí eré ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.[2][3][4] Ó bẹ̀rẹ̀ eré ṣíṣe ní ọdún 2004 nígbà tí ó ṣí wà ní ilé ẹ̀kọ́ gíga tí Lagos State University.[5] Óun àti òṣèré Bọ́láńlé Nínálowó jẹ́ mọ̀lẹ́bí.[6]

Àṣàyàn àwọn eré tí ó tí ṣe
Àwọn Ìtọ́kàsi
Wikiwand - on
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Remove ads