Rym Breidy

From Wikipedia, the free encyclopedia

Rym Breidy
Remove ads

Rym Saidi Breidy (Lárúbáwá: ريم بريدي)(bíi ni ọjọ́ kọkànlélógún oṣù kẹfà ọdún 1986) jẹ́ mọ́dẹ́lì àti òṣèré lórílẹ̀-èdè Tunisia.

Quick Facts Ọjọ́ìbí, Orílẹ̀-èdè ...
Remove ads

Iṣẹ́

Rym Breidy bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí mọ́dẹ́lì ní ọdún 2003 lẹ́hìn tí ó gbé igbá orókè níbi ìdíje Elite Model Look Tunisia. Ní ọdún 2006, ó gbé ipò kìíní níbi ìdíje MISSION FASHION[2]. Ní ọdún 2007, ó di mọ́dẹ́lì fún MP Models[3]. Ó ti si ṣé gẹ́gẹ́ bí mọ́dẹ́lì fún Profile models ní London,[4] Women Model Management ní Milan,[5] MP Management ní Paris, One.1 Management ní New York City,[6] Munich Models ní Germany,[7] MP Mega ní Miami.[8]. Ó gbajúmọ̀ ni Italy fún ipa Madre Natura[9][10] tí ó kó nínú eré Ciao Darwin. Ó jẹ́ àmbásẹ́dọ̀ fún ilé iṣẹ́ Traveltodo láti ọdún 2013.[11][12][13][14]

Remove ads

Ìgbésí ayé rẹ̀

Ní ọjọ́ kerìndínlọ́gún oṣù keje ọdún 2017, ó ṣe ìgbéyàwó pẹ̀lú Wissam Breidy.[15] Ó ti bí ọmọ bìnrin méjì.[16][17]

Àwọn Ìtọ́kàsi

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads