Zambia

From Wikipedia, the free encyclopedia

Zambia
Remove ads

Orílẹ̀-èdè Olómìnira Zambia (pípè /ˈsæmbiə/) jẹ́ Orílẹ̀-èdè tileyika kan ni Apaguusu Afrika. Awon Orílẹ̀-èdè tó súnmọ ni Orílẹ̀-èdè Olómìnira Toseluarailu ile Kongo ní àríwá , Tanzania ni ariwa-ilaorun, Malawi ni ilaorun, Mozambique, Zimbabwe, Botswana, ati Namibia ni guusu, ati Angola ni iwoorun. Oluilu re ni Lusaka, tó bùdó sí apá gúúsù-arin ibe.

Quick Facts Republic of Zambia, Olùìlú àti ìlú tótóbijùlọ ...
Remove ads

Itokasi

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads