Sade Adu

From Wikipedia, the free encyclopedia

Sade Adu
Remove ads

Helen Fọláṣadé Adú ni wọ́n bí ní Ọjọ́ kẹrìndínlógún oṣù kìíní ọdún 1959 (16th January 1959) jẹ́ olórin, oǹkọ̀wé orin àti òṣèré sinimá àgbéléwò ará orílẹ̀-èdè Gẹ̀ẹ́sì, ṣùgbọ́n tí ó jẹ́ ọmọ bíbí ìlú Ìbàdàn ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà. [1]. [2]

Quick facts Background information, Orúkọ àbísọ ...




Remove ads

Àwọn Ìtọ́kasí

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads