Sahara Reporters
From Wikipedia, the free encyclopedia
Remove ads
Sahara Reporters jẹ́ ilé-iṣẹ́ ataròyìn ní ìlú New York City tó gbájúmọ́ àwọn ìròyìn nípa àwọn ará ìlú, tí ó sì máa ń rọ àwọn ènìyàn láti máa jábọ̀ àwọn ìròyìn nípa ìwà ajẹ́bánu, ìwà àtẹ̀mẹ́rẹ̀ ẹ̀tọ́ ọmọ ènìyàn àti àwọn ìwà burúkú àwọn ẹgbẹ́ òṣèlú ní Africa, pàápàá jùlọ, Nigeria.[2][3] Ilé iṣẹ́ Sahara Reporters gbájúmọ́ títú àṣírí ìwà àjẹbáni àti ìwà burúkú àwọn ìjọba.
Remove ads
Àwọn Ìtọ́kasí
Wikiwand - on
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Remove ads