Shirley Chisholm

Olóṣèlú From Wikipedia, the free encyclopedia

Shirley Chisholm
Remove ads

Shirley Anita St. Hill Chisholm (November 30, 1924 – January 1, 2005) je oloselu, oluko ati olukowe ara Amerika.[3] O je omo-egbe Ile Asofin, nibi to ti soju fun Agbegbe Ile Asofin 12k New York fun igba emeje lati 1969 de 1983. Ni 1968, o di obinrin alawodudu akoko to je didiboyan si Ile Asofin Amerika.[4]

Quick facts Asíwájú, Arọ́pò ...
Remove ads

Itokasi

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads