Ọkọ̀-àlọbọ̀ Òfurufú Discovery

From Wikipedia, the free encyclopedia

Ọkọ̀-àlọbọ̀ Òfurufú Discovery
Remove ads

Ọkọ̀-àlọbọ̀ Òfurufú Discovery (Orbiter Vehicle Designation: OV-103) je ikan ninu awon oko-afiyipo meta ti won sise lowolowo ninu awon Ọkọ̀-àlọbọ̀ Òfurufú ti NASA, to je ile-ise ofurufu ti orile-ede Amerika.[2] (Awon meji yioku ni Atlantis ati Endeavour.) Nigba to koko sise ni 1984, Discovery je oko-afiyipo keta sugbon loni ohun ni eyi to pejulo lenu ise. Discovery ti se iranlose fun iwadi ati fun isoapapo ISS.

Quick facts DiscoveryOV-103, OV designation ...
Remove ads

Itokasi

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads