Tanzania

From Wikipedia, the free encyclopedia

Tanzania
Remove ads

Tànsáníà tabi Orílẹ̀-èdè Olómìnira Ìṣọ̀kan ilẹ̀ Tànsáníà (pípè /ˌtænzəˈniːə/; Swahili: Jamhuri ya Muungano wa Tanzania)[11] je orile-ede ni Ilaoorun Afrika to ni bode mo Kenya ati Uganda ni ariwa, Rwanda, Burundi ati orile-ede Olominira Toseluarailu ile Kongo ni iwoorun, ati Zambia, Malawi ati Mozambique ni guusu. Awon bode Tansania ni ilaorun ja si Okun India.

Quick Facts Orílẹ̀-èdè Olómìnira Ìṣọ̀kan ilẹ̀ TànsáníàUnited Republic of Tanzania Jamhuri ya Muungano wa Tanzania (Swahili), Olùìlú ...
Remove ads

Awon agbegbe

Thumb
Regions of Tanzania.

Awon agbegbe Tanzania niwonyi: Arusha · Dar es Salaam · Dodoma · Iringa · Kagera · Kigoma · Kilimanjaro · Lindi · Manyara · Mara · Mbeya · Morogoro · Mtwara · Mwanza · Pemba North · Pemba South · Pwani · Rukwa · Ruvuma · Shinyanga · Singida · Tabora · Tanga · Zanzibar Central/South · Zanzibar North · Zanzibar Urban/West

Remove ads

Àwọn ìtọ́kasí

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads