TLC

From Wikipedia, the free encyclopedia

TLC
Remove ads

TLC ni ẹgbẹ́ olórin obìnrin ará Amẹ́ríkà tí ọmọ ẹgbẹ́ jẹ́ Tionne "T-Boz" Watkins, Lisa "Left Eye" Lopes, àti Rozonda "Chilli" Thomas. Wọ́n dáa sílẹ̀ ní ìlú Atlanta, Georgia ní ọdún 1991, ẹgbẹ́ náà yọrí sí rere ní ìgbà àwọn ọdún 1990s.[3] Wọ́n ṣe orin mẹ́sàn tó bọ́ sí top-ten hits lórí Billboard Hot 100, nínú wọn ni mẹ́rin tó bọ́ sí no. 1 "Creep", "Waterfalls", "No Scrubs", àti "Unpretty".[4] Àwo orin wọn mẹ́rin ló pawó platinum, nínú wọn ni CrazySexyCool (1994), tó gba ìwé-ẹ̀rí ìpawó diamondi látọwọ́ àjọ Recording Industry Association of America (RIAA).[5] TLC tún ni ẹgbẹ́ akọrin R&B àkọ́kọ́ tó gba ìwé-ẹ̀rí ìpawó Million látọwọ́ àjọ Recording Industry Association of Japan (RIAJ) fún FanMail (1999).[6]

Thumb
Ẹgbẹ́ TLC lórí ìtàgé ní ọdún 2016
Quick Facts Background information, Wọ́n tún mọ̀ọ́ bíi ...


Remove ads

Ìtọ́kasí

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads