Tẹlifísàn

From Wikipedia, the free encyclopedia

Tẹlifísàn
Remove ads
Thumb
Tẹlifísàn

Kini Afigbebanisoro amohunmuaworan? (tẹlifísàn)

Thumb

Tẹlifísàn tabi Àfigbéwòran (TV) je afigbebanisoro amohunmuaworan to un se igbejade ati to n se igbawole aworan arekoja, ki ba je alawo funfun ati dudu tabi ti alawo ati àwọ̀ orisirisi.

Kini mo le wo lori afigbebanisoro amohunmuaworan tabi tẹlifísàn bi omo Nigeria tabi Yoruba?

O je orisirisi ohun ti o le wo lori afigbebanisoro amohunmuaworan (tẹlifísàn). O le wo "Mount Zion" o je eré (fiimu) gbajumo ni èdè Gẹ̀ẹ́sì ati ni èdè Yoruba.

Itokasi

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads