Mount Zion Faith Ministries

From Wikipedia, the free encyclopedia

Remove ads

Kini fiimu Mount Zion?

Mount Zion Faith Ministries jé isẹ́ ìránṣẹ́ eré ìtàgé tí a ti owo Evang. Mike Bamiloye àti Gloria Bamiloye dálè ní odun 1985[1] Ète dídá isé iranse na kalè ni(gege bi Olùdásílè Mike Bamiloye sé so) láti se isé ihinrere kari aye àti láti sé igbero ìjo Olorun

Thumb
Mike Bamiloye

Ní ọjọ́ kọkànlá, osù keje, ọdún 1986, isé ìránṣẹ́ e na ṣe eré ìtàgé àkọ́kọ́ ní ilé ìwé St. Margaret girls granted school ní Ilesha, ní odún tó tẹ́le, Mike Bamiloye Kọ̀wé fi isé sílẹ́ láti gbájúmọ́ iṣé ìránṣẹ́ Mount Zion Faith Ministries[2] Fiimu àkókò tí Mount Zion Faith Ministries se jáde ni "the inprofitable servant" ní odun 1990[3], léyìn ìgbàyí, wón tí sé olé ni igba(200) fiimu jáde. Òkan lára àwon fiimu won tó gbajugbaja ni "agbára nlá"

Remove ads

Àwon Ìtọ̀kasí

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads