Tibet

From Wikipedia, the free encyclopedia

Tibet
Remove ads

Tibet je agbegbe ni Ásíà ati agbegbe to n fa ijawaye ni ariwa Himalaya. Ibe ni awon omo Tibet n gbe ati awon eya eniyan miran bi Monpas ati Lhobas, Hui ati Han. Tibet ni agbegbe to gajulo laye pelu igasoke 4,900 metres, won n pe bi aja aye.[1]

Thumb
Remove ads

Itokasi

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads