Tim Burton
Òṣèré Ọmọ Orílẹ̀-èdè America From Wikipedia, the free encyclopedia
Remove ads
Timothy Walter Burton[lower-alpha 1] (tí a bí ní ọjọ́ Kàrùnlélógún oṣù kẹjọ ọdún 1958) jẹ́ olùṣe fíìmù àti ayàwòrán ọmọ Amẹ́ríkà. Ọ̀pọ̀ mọ̀ọ́ fún pípinlesẹ̀ àṣà Goth ní ilé iṣẹ́ fíìmù Amẹ́ríkà. Ara àwọn eré tí ó ti gbé jáde ni Beetlejuice (1988), Edward Scissorhands (1990), The Nightmare Before Christmas (1993), Ed Wood (1994), Sleepy Hollow (1999), Corpse Bride (2005), Sweeney Todd: The Demon Barber of Fleet Street (2007), Dark Shadows (2012), Wednesday (2022). Burton tún dárí àwọn eré bi Batman (1989), Batman Returns (1992), Planet of the Apes (2001), Big Fish (2003), Charlie and the Chocolate Factory (2005), Alice in Wonderland (2010) àti Miss Peregrine's Home for Peculiar Children (2016).
Remove ads
Àwọn Ìtọ́kasí
Wikiwand - on
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Remove ads
