Tracee Ellis Ross

Òṣèré Ọmọ Orílẹ̀-èdè America From Wikipedia, the free encyclopedia

Tracee Ellis Ross
Remove ads

Tracee Ellis Ross (oruko abiso Tracee Joy Silberstein; October 29, 1972) je osere, ologe, alawada ati olootu eto telifisan to gbajumo fun ere re bi Dr. Rainbow Johnson lori ere awada ile-ise telifisan ABC Black-ish.[1]

Quick facts Ọjọ́ìbí, Iléẹ̀kọ́ gíga ...

Tracee Ellis Ross je ikan ninu awon omo Diana Ross.

Remove ads

Itokasi

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads