Tsẹ́kì Olómìnira (Tsẹ́kíà; pípè /ˈtʃɛk/(listen)[10]chek; Tsẹ́kì:[Česká republika]error: {{lang}}: text has italic markup (help), Àdàkọ:IPA-cs, short form ČeskoÀdàkọ:IPA-cs) je orile-ede ni Arin Europe.[11] O ni bode mo Poland ni ariwailaorun, Jemani ni iwoorun ati ariwaiwoorun, Austria ni guusu ati Slovakia ni ilaorun. Orile-ede Tseki Olominira ti je omo egbe NATO lati 1999 ati Isokan Europe lati 2004. Bakanna o tun je omo egbe Agbajo fun Abo ati Ifowosowopo ni Europe (OSCE).
Karlštejn Castle in the Central Bohemian Region, founded in 1348 by Charles IV.Tábor, a town in the South Bohemian Region, founded in 1420 by the Hussites.Charles IV, 1316 – 78, eleventh king of Bohemia. Charles IV was elected the Největší Čech (Greatest Czech) of all time.[9]