UNESCO

From Wikipedia, the free encyclopedia

UNESCO
Remove ads

UNESCO dúró fún United Nations Educational, Scientific and Cultural Organizationèdè Gẹ̀ẹ́sì (Àjọ Ẹ̀kọ́, Sáyẹ́ńsì àti Àṣà tí Ìṣọ̀kan àwọn Orílẹ̀-èdè)

Quick facts United Nations Educational, Scientific and Cultural Organization, Irú ...

Wọ́n dá UNESCO sílẹ̀ ní ọdún 1945 lẹ́yìn League of Nations' International Committee on Intellectual Cooperation.[1] Àwọn àjọ òǹdásílẹ́ UNESCO, ní èyí tí ó wáyé nípa ìṣẹ̀lẹ̀ World War II, láti mú ìtẹ̀síwájú àlàáfíà, ìdàgbàsókè tó yanrantí àti ẹ̀tọ́ ọmọ ènìyàn nípa mímú ìbáṣepọ̀ àti ìfọ̀rọ̀jomitoro-ọ̀rọ̀ láàárín àwọn orílẹ̀-èdè.


Remove ads

Itokasi

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads