Viktor Yanukovych
From Wikipedia, the free encyclopedia
Remove ads
Viktor Fedorovych Yanukovych (Ukrainian: Віктор Федорович Янукович (ìrànwọ́·ìkéde) Viktor Fedorovyč Janukovyč; Rọ́síà: Виктор Фёдорович Янукович) (ojoibi July 9, 1950, Yenakiieve, Donetsk Oblast) ni Aare ekerin orile-ede Ukraine lati 25 February, 2010.
Yanukovych je Gomina igberiko Donetsk Oblast lati 1997 de 2002. Yanukoych tun wa ni ipo Alakoso Agba ile Ukraine lemeji lati November 21, 2002 de December 31, 2004 labe Aare Leonid Kuchma ati lati August 4, 2006 titi de December 18, 2007 labe Aare Viktor Yushchenko, to je alatako re ninu idiboyan Aare 2004 nibi to gba ipo keji.
![]() |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Remove ads
Itokasi
Wikiwand - on
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Remove ads