Waje

Akọrin obìnrin From Wikipedia, the free encyclopedia

Waje
Remove ads

Waje tí orúko àbíso rè njé Aituaje Iruobe jé olórin ará Naijiria. Ó kókó gba ìdánimò léyìn ìgbà tí ó kópa nínú àtúnse orin "Omoge Mi" tíP-Square ko. Wáje tún kópa nínú orin won tí ó gbajú gbajà tí ó nje "Do Me". Láfikún, ó fi ohùn rè kún orin "Thief my Kele" tí Banky W "One Naira" tí ó je Ti M.I

Quick facts Background information, Orúkọ àbísọ ...

[1]

Ni odun 2016, Waje je okan lara awon adajo merin ninu eto akoko

The Voice Nigeria. Nigba to di odun 2018, Waje farahan loorekoore ninu fiimu Africa Magic telenovela, Battleground.[2]

[3]

Remove ads

Itokasi

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads