Wema Sepetu
From Wikipedia, the free encyclopedia
Remove ads
Wema Sepetu (bíi ni ọjọ́ kejìdínlógbọ̀n oṣù kẹsàn-án ọdún 1990) jẹ́ òṣèré lórílẹ̀ èdè Tanzania.[1][2]
Iṣẹ́
Ní ọdún 2011, ó gbé eré Superstar kalẹ̀ tí ó sọ̀rọ̀ nípa ìtàn ìfẹ́ òhun àti Diamond Platnumz[3][4]. Ní ọdún 2014, òun àti Van Vicker jọ gbé eré Day After Death jáde.[5][6] Ní ọdún 2013, ó gbé ilé iṣẹ́ rẹ̀ kalẹ̀ tí ó pè ní Endless Fame Production.[7][8]
Àṣàyàn eré rẹ̀
Remove ads
Àmì ẹ̀yẹ
Àwọn Ìtọ́kàsi
Wikiwand - on
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Remove ads