Wesley Snipes
Òṣèré Ọmọ Orílẹ̀-èdè America From Wikipedia, the free encyclopedia
Remove ads
Wesley Trent Snipes (ọjọ́ìbí July 31, 1962) ni òṣeré, olùkọ̀wé, olùdarí àti olóòtú fílmù ará Amẹ́ríkà. Ó gbajúmọ̀ fún ìṣeré rẹ̀ nínú àwọn fílmù bíi New Jack City (1991), White Men Can't Jump (1992), Passenger 57 (1992), Demolition Man (1993), U.S. Marshals (1998) àti ẹ̀dá Marvel Comics tó únjẹ́ Blade nínú fílmù apá mẹ́ta Blade (1998–2004), The Expendables 3 (2014 film). Àti fún The Player (2015).
Remove ads
Itokasi
Wikiwand - on
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Remove ads