Yẹmí Àlàdé
Akọrin obìnrin From Wikipedia, the free encyclopedia
Remove ads
Yẹmí Eberechi Àlàdé (ọjọ́ìbí 13 March 1989), tó gbajúmọ̀ pẹ̀lú orúkọ ìkọrin rẹ̀ bíi Yẹmí Àlàdé, ni akọrin Afropop omo orilede Nàìjíríà. Ó kọ́kọ́ gbajúmọ̀ nígbà tó gbẹ̀yẹ nínú ìdíje Peak Talent Show ní ọdún 2009, ó sì gbé àwo-orin rẹ̀ "Johnny" jáde ní ọdún 2014.[1][2][3] Bábá rẹ̀ jẹ́ ọmọ Yoruba, ìyá rẹ̀ jẹ́ ará ẹ̀yà Igbo.[4]
Remove ads
Itokasi
Wikiwand - on
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Remove ads

