Zineb Triki
From Wikipedia, the free encyclopedia
Remove ads
Zineb Triki (Lárúbáwá: ﺯﻳﻨﺐ ﺗﺮﻳﻜﻲ; ti a bi ni odun 1980) je osere ede French ti owa lati ilu Morocco, o je olokiki fun ipa re ninu jara Èdè Faransé titi Nadia El Mansour, ti akole re je The Bureau.
Won bi Zineb Triki ni odun 1980, ni ilu Morocco, o lo si ile eko elede Faranse ni bi ti oti ko imo ere ori itage ati ijo. Ni igba ti o pe omo odun medogun, o lo si ilu Parisi[1]
O gba oye-oye ni eko oselu lati owo McGill University ni ilu Kánádà. O se ise pelu UN, ni New York ni odun 2003[2] O gba oye masitas ninu eto oselu lati Sorbonne University ni ilu Parisi, lehin na ogba oye mastas imiran ninu iselopo ni Paris.[3]
Triki bere ise osere ni karakara lati odun 2009, pelu ipa kekere ninu 14h05 ati The Misadventures of Franck and Martha. I pa akoko ti oko ninu ere Deux fenêtres in 2013 ati La Marche verte (2016).[4] Jara telisonu The Bureau ni ofun ni okiki fun ipa re gegebi Nadia El Mansour.
Ipa re gege bi Iya Nassim ninu ere De toutes mes forces je ipa o tan ina, pelu bi o se le to.[5]
Remove ads
Asayan ere
Triki ti ko ipa ninu awo ere ati jara wonyi;[6]
- 2009 : 14h05
- 2009 : The Misadventures of Franck and Martha
- 2013 : Deux fenêtres
- 2014 : Hard Copy (Awada ori itage)
- 2016 : Glacé (Jara) - Charlène
- 2016 : La Marche verte (Fiimu)
- 2015 – 2020 : The Bureau (Jara) - Nadia El Mansour
- 2017 : De toutes mes forces (Fiimu) - Nassim's mother
- 2017 : Les grands esprits (Fiimu) - Agathe
- 2020 : Homeland (Jara) - Judge Haziq Qadir
Remove ads
Awọn itọkasi
Wikiwand - on
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Remove ads