Map Graph

CERN

CERN tàbí European Organization for Nuclear Research, lasan bi CERN tabi Cern jẹ́ àgbájọ akáríayé tí iṣẹ́ rẹ̀ ni láti bòjúsí ìṣeṣẹ́ ilé-àdánwò físíksì eruku tóbijùlọ lágbàáyé, tó wà ní àríwáìwọ̀òrùn àdúgbò Geneva ní ẹ̀bá bodè Fránsì àti Swítsàlandì. Ó jé dídásílẹ̀ ní 1954, àgbájọ náà ní orílẹ̀-èdè ọmọẹgbẹ́ Europe 20.

Read article
Fáìlì:CERN_logo_badge.svgFáìlì:CERN_member_states.svgFáìlì:Cernfounders.pngFáìlì:CERN1999.png