CERN

From Wikipedia, the free encyclopedia

CERNmap
Remove ads

CERN tàbí European Organization for Nuclear Research (Faransé: Organisation européenne pour la recherche nucléaire), lasan bi CERN tabi Cern (play /ˈsɝn/; ìpè Faransé: [sɛʁn]; e wo Ìtàn) jẹ́ àgbájọ akáríayé tí iṣẹ́ rẹ̀ ni láti bòjúsí ìṣeṣẹ́ ilé-àdánwò físíksì eruku tóbijùlọ lágbàáyé, tó wà ní àríwáìwọ̀òrùn àdúgbò Geneva ní ẹ̀bá bodè Fránsì àti Swítsàlandì (46°14′3″N 6°3′19″E). Ó jé dídásílẹ̀ ní 1954, àgbájọ náà ní orílẹ̀-èdè ọmọẹgbẹ́ Europe 20.

Quick facts European Organization for Nuclear Research Organisation européennepour la recherche nucléaire, Ìdásílẹ̀ ...
Thumb Thumb
The 12 founding member states of CERN in 1954 a[] (map borders from 1989)
54 years after its foundation, membership to CERN increased to 20 states, 18 of which are also EU members in 2010
Remove ads

Itokasi

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads