Ìgbẹ́ Ènìyàn
From Wikipedia, the free encyclopedia
Ìgbẹ́ Ènìyàn tàbí Imí jẹ́ àwọn ohun óúnjẹ tí a jẹ tí ó dà àmọ́ tì kò dà tán nínú ikùn tàbí agbẹ̀du ènìyàn.[1][2] Ìgbẹ́ ma ń ní àwọn èròjà àìfojúrí tí wọ́n ń pè ní (bacteria), (biliribin) ati díẹ̀ (epithelial) nínú àwon sẹ́ẹ̀lì tí wọ́n ti kú,[1] lẹ̀yìn tí yóò sì jáde láti ẹnu ihò-ìdí, tí a ó sì ma pèé ní Ìgbẹ́ nígbà tí a bá yàá sílẹ̀ tán