Barnabas Andyar Gemade
Olóṣèlú From Wikipedia, the free encyclopedia
Olóṣèlú From Wikipedia, the free encyclopedia
Barnabas Andyar Gemade jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí wọ́n dìbò yàn wọlé gẹ́gẹ́ bí aṣojú àríwá-ìwọorùn Ìpínlẹ̀ Bauchi ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà ti ilẹ̀ Nàìjíríà.[1] Ó jẹ́ aṣojú ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin lẹ́yìn tí ó wọlé látàrí ètò ìdìbò ti oṣù kẹrin ọdún 2011 lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú People's Democratic Party.[2][3][4]
Barnabas Andyar Iyorhyer Gemade | |
---|---|
Àwòrán Barnabas Andyar Gemade | |
Aṣojú ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin Nàìjíríà | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga Oṣù karún ọdún 2011 | |
Asíwájú | Joseph Akaagerger |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 4 Oṣù Kẹ̀sán 1948 Ìpínlẹ̀ Benue, Nàìjíríà |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | People's Democratic Party (PDP) |
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Every time you click a link to Wikipedia, Wiktionary or Wikiquote in your browser's search results, it will show the modern Wikiwand interface.
Wikiwand extension is a five stars, simple, with minimum permission required to keep your browsing private, safe and transparent.