David Mark
Olóṣèlú Naijiria / From Wikipedia, the free encyclopedia
David Alechenu Bonaventure Mark (bíi ní Oṣù kẹrin Ọdún 1948) jẹ́ ológun tí ó ti fẹ̀hìntì àti olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí wọ́n dìbò yàn wọlé gẹ́gẹ́ bí aṣojú Ìpínlẹ̀ Benue ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà ti ilẹ̀ Nàìjíríà. Ó jẹ́ aṣojú ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin lẹ́yìn tí ó wọlé látàrí ètò ìdìbò ti oṣù kẹrin ọdún 2007 lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú People's Democratic Party.[2] Ó jẹ́ ààrẹ ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin.[3][4]
Quick Facts Ààrẹ ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà ti ilẹ̀ Nàìjíríà, Deputy ...
David Alechenu Bonaventure Mark | |
---|---|
Ààrẹ ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà ti ilẹ̀ Nàìjíríà | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga Ọjọ́ kẹfà Oṣù kẹfà Ọdún 2007 | |
Deputy | Ike Ekweremadu |
Asíwájú | Ken Nnamani |
Constituency | Gúúsù Benue |
Ààrẹ ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà ti ilẹ̀ Nàìjíríà. | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga Oṣù kẹrin Ọdún 2003 | |
Gómínà Ìpínlẹ̀ Niger | |
In office Oṣù kínín 1984 – 1986 | |
Asíwájú | Awwal Ibrahim |
Arọ́pò | Garba Ali Mohammed |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | Oṣù kẹrin 1948 Zungeru, Niger State[1] |
Ọmọorílẹ̀-èdè | Ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | PDP |
Close