Katerina Sakellaropoulou[1] (Gíríkì: Κατερίνα Σακελλαροπούλου, [kateˈrina sacelaroˈpulu]; ọjọ́ìbí 30 May 1956) ni Ààrẹ ilẹ̀ Gírìsì.[2] Wọ́n dìbóyán láti dípò Ààrẹ Prokopis Pavlopoulos ní 22 January 2020, látọwọ́ Hellenic Parliament. Kú wọn ó tó dìbóyán bíi Ààrẹ ilẹ̀ Gírìsì, ó siṣẹ́ bíi Ààrẹ Ìgbìmọ̀ Iṣẹ́ Orílẹ̀-èdè, tó jẹ́ ilé-ẹjọ́ òsìṣẹ́ ìjọba ní Gírìsì.

Quick Facts President of Greece, Alákóso Àgbà ...
Katerina Sakellaropoulou
Κατερίνα Σακελλαροπούλου
Thumb
President of Greece
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
13 March 2020
Alákóso ÀgbàKyriakos Mitsotakis
AsíwájúProkopis Pavlopoulos
President of the Council of State
In office
17 October 2018  11 February 2020
Vice PresidentAthanasios Rantos [Àdàkọ:Separated entries]
AsíwájúNikolaos Sakellariou [Àdàkọ:Separated entries]
Arọ́pòAthanasios Rantos [Àdàkọ:Separated entries]
Vice President of the Council of State
In office
22 October 2015  17 October 2018
ÀàrẹNikolaos Sakellariou [Àdàkọ:Separated entries]
AsíwájúNikolaos Sakellariou [Àdàkọ:Separated entries]
Arọ́pòAthanasios Rantos [Àdàkọ:Separated entries]
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí
Aikaterini Sakellaropoulou

30 Oṣù Kàrún 1956 (1956-05-30) (ọmọ ọdún 68)
Thessaloniki, Greece
Ẹgbẹ́ olóṣèlúIndependent
ResidencePresidential Mansion
EducationUniversity of Athens
University of Paris II Panthéon-Assas
SignatureThumb
Close

Àwọn ìtọ́kasí

Wikiwand in your browser!

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Every time you click a link to Wikipedia, Wiktionary or Wikiquote in your browser's search results, it will show the modern Wikiwand interface.

Wikiwand extension is a five stars, simple, with minimum permission required to keep your browsing private, safe and transparent.