From Wikipedia, the free encyclopedia
Màríà (èdè Aramaiki, èdè Heberu: מרים, Maryām Miriam; èdè Arabu:مريم, Maryam), ti awon omo leyin Kristi n pe ni Mariamo, Maria Wundia tabi Maria Mimo ati nigba miran Madonna, je obinrin Ju ara Nazareth ni Galilee, ti Majemu Tuntun[Mt. 1:16,18–25] [Lk. 1:26–56] [2:1–7] tokasi gege bi iya Jesu Kristi. Awon musulumi na un pe ni Maria Mimo tabi Syeda Mariam, to tumosi Màríà Ìyá Wa. Majemu Tuntun se apejuwe re bi wundia (Griiki παρθένος, parthénos).[3] Awon Elesin Kristi gbagbo pe o loyun Jesu nipa Emin Mimo.
Màríà, Ìyá Jésù Mary, Mother of Jesus | |
---|---|
The Madonna in Sorrow, by Sassoferrato, 17th century. | |
Theotokos ("Mother of God") Blessed Virgin Mary Umm Issa ("Mother of Jesus") Saint Mary | |
Born | unknown; celebrated 8 September [1] |
Died | unknown; See Assumption of Mary |
Venerated in | Anglican Communion Eastern Orthodoxy Lutheranism[2] Oriental Orthodoxy Catholic Church Recognized and honored (not venerated) in: Protestantism |
Major shrine | See Shrines to the Virgin Mary |
Feast | Mary is commemorated on as many as 25 different days. The most universally observed are:
25 March – The Annunciation
15 August – The Assumption (Catholicism) |
Patronage | See Patronage of the Blessed Virgin Mary |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Every time you click a link to Wikipedia, Wiktionary or Wikiquote in your browser's search results, it will show the modern Wikiwand interface.
Wikiwand extension is a five stars, simple, with minimum permission required to keep your browsing private, safe and transparent.