Àwọn Bàhámà

From Wikipedia, the free encyclopedia

Àwọn Bàhámà
Remove ads

Àwọn Bàhámà (pípè /ðə bəˈhɑːməz/ ( listen)) tabi lonibise bi Orílẹ̀-èdè Àjọni ilẹ̀ awọn Bàhámà, je orile-ede elede Geesi to ni awon erekusu 29, 661 cays, ati 2,387 erekusu kekere 2,387 (apata). O budo si inu Okun Atlantiki ni ariwa Kuba ati Hispaniola (Dominiki Olominira ati Haiti), ariwaiwoorun awon Erekusu Turks ati Caicos, ati guusuilaorun orile-ede Awon Ipinle Aparapo ile Amerika (nitosi ipinle Florida). Apapo iye aala ile re je 13,939 km2 (5,382 sq. mi.), pelu idiye olugbe to to 330,000. Oluilu re ni Nassau. Bi jeografi, awon Bahama wa ni asopo erekusu kanna bi Kuba, Hispaniola (Dominiki Olominira ati Haiti) ati Awon Erekusu Turks ati Caicos.

Quick facts Commonwealth of The Bahamas Àjọni ilẹ̀ àwọn Bàhámà, Olùìlú ...

Awon onibudo ibe tele ni awon Taino ti Arawaka, awon Bahama ni ibi ti Columbus koko gunle si ni Ile Aye Tuntun ni 1492. Botilejepe awon ara Spein ko se amunisin awon Bahama, won ko awon Lucaya abinibi ibe (eyi ni oruko ti awon Taino Bahama unpe ara won) lo si oko eru ni Hispaniola. Lati 1513 de 1650 enikankan ko gbe ori awon erekusu yi, ko to di pe awon olumunisin ara Britani lati Bermuda tedo si erekusu Eleuthera.

Remove ads

Itoka

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads