Ọlọ

From Wikipedia, the free encyclopedia

Ọlọ
Remove ads
Àyọkà yìí jẹ mọ́ nípa ohun èlò ìdáná. Fún other uses, ẹ wo: Batan.

Ọlọ ni ó jẹ́ ọ̀kan lára ohun èlò Ilé ìdáná tí wọ́n ma ń lò láti pèsè tàbí lọ oríṣiríṣi nkan bí ata, ẹ̀wà, ẹ̀gúsí, àlùbọ́sà àti bẹ́ẹ̀ bẹ́é lọ.

Thumb

Ìrísí rẹ̀

Ọlọ ní ojú tó tẹ́ pẹrẹsẹ, tí ó sì mọ níwọ̀n tí ó ṣeé gbé láti ibìkan sí ibòmíràn. Ẹ̀wé, ọlọ ma ń ní ọmọ ọlọ tí ó ṣé gbámú lẹ̀lú ọeọ́ kna tàbí ọwọ́ méjèèjì nígbà tí a bá fẹ́ lòó.

Ohun tí wọ́n fi ń ṣe Ọlọ

Láyé àtijọ́, àpáta tí ó sàn ni wọ́n ma ń lò láti fi ṣe ọlọ, tí wọn yóò sì wá òkúta tí ó tóbi mọ nìwọ̀n tí wọ́n lè fi ṣe ọmọ ọlọ. Àmọ́ láyé òde òní, diẹ̀ nínú àwọn ènìyàn ni wọ́n tún bìkítà láti máa lo àpáta láti fi ṣe ọlọ tàbí ọmọ ọlọ mọ́, wọ́n ti ń lo ẹ̀rúnrún tàbí àfọ́kù àpáta tó ti di iyẹ̀pẹ̀ àti símẹ́ntì ìkọ́lé ṣe ọlọ ní ọ̀nà àrà àti ti ìgbà lódé tí ó s8 ń ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí ti àpáta ayé àtijọ́. Ó kan jẹ́ wípé àwọn ẹ̀rún iyẹ̀pẹ̀ kọ̀ọ̀kan ma ń wà nínú ohun tí a bá lọ̀ lórí ọlọ ìgbà lódé ni. [1][2]

Thumb
Using a small batán to grind a green pepper

[3][4] [5].[6]

Remove ads

Àwọn Ìtọ́kasí

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads