Ata

From Wikipedia, the free encyclopedia

Ata
Remove ads

Ata ni ohun èso tí a ká tí a sì fi pèsè yálà ohun jíjẹ bí Ọbẹ̀ tàbí mímu mìíràn kí ó le ta lẹ́nu kí ó sì lè ṣe ànfàní fún ará. Pàá pàá jùlọ lásìkò òtútù tàbí ọ̀gìnìntìn. [1][2]

Thumb
Capsicum annuum

Oríṣi ata to wà

Àwọn Ìtọ́kasí

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads