Àwọn ẹranko afọmúbọ́mọ ni àwọn ẹranko elégungun tí wọ́n wà nínú ìtòsílẹ̀ ẹgbẹ́Mammalia (/məˈmeɪliə/), wọ́n ṣe é dámọ̀ pẹ̀lú ọyàn tí àwọn abo wọn ní láti ṣe mílíkì fún ọmọ-ọwọ́ wọn.
Quick Facts Ìṣètò onísáyẹ́nsì [ e ], Living subgroups ...
Àwọn eranko afọmúbọ́mọ Mammalia
Temporal range: Late Triassic–Recent; 225 or 167–0 Ma See discussion of dates in text