Ahọ́n

From Wikipedia, the free encyclopedia

Ahọ́n
Remove ads

Ahọ́n jẹ́ ẹ̀yà ara ìfọ̀ tí ó jẹ́ iṣan tí ó wà ní inú ẹnu ènìyàn tàbí ẹranko tí ó jẹ́ eléegun lẹ́yìn.

Quick Facts Details, Precursor ...
Remove ads

Iṣẹ́ tí ahọ́n ń ṣe

Ahọ́n ń ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí ẹ̀ya ara tí ọmọ ènìyàn ń lò fún ìbánisọ̀rọ̀, jíjẹ óúnjẹ, tí gbogbo ẹranko tókù sì ń lò ní ìlànà kan náà, yàtọ̀ sí ìbásisọ̀rọ̀ bí ti ọmọnìyàn. Ahọ́n wúlò púpọ̀ fún jíjẹ àti dídà óúnjẹ nínú àgọ́ ara nítorí àwọn èròjà amú óúnjẹ dà tí wọ́n ń pè ní (enzyme). Lára ahọ́n náà ni ìtọ́wò tí a fi ń mọ adùn àti kíkan. Ahọ́n tún sábà ma ń tutù látàrí èròjà tí ó ń pèsè itọ́ tí ó wà lára rẹ̀. Ahọ́n tún ma ń ṣe ìmọ́ tótó ẹnu nígba gbogbo, pàá pàá jùlọ eyín. [2] Kókó iṣẹ́ ahọ́n ni kí ó ṣètò ìró ohùn di ọ̀rọ̀ lára ènìyàn àti ohùn lásán lára àwọn ẹranko tókù.

Remove ads

Ọ̀nà tí ahọ́n pín sí

Ahọ́n ọmọnìyàn pín sí ọ̀nà méjì, àkọ́kọ́ ni Ìpín ibùsọ̀rọ̀, èyí wá ní ọwọ́ iwájú nígbà tí ìpín kejì jẹ́ tááná tí ó wà lọ́ ẹ̀yìn mọ́ ọ̀nà ọ̀fin. Apá ọ̀tún àti apá òsì ni iṣan tí ó nà tẹ́ẹ́rẹ́ tí ó ń gbé ẹ̀jẹ̀ kiri gbogbo ara ahọ́n náà.

Àwọn Ìtọ́ka sí

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads