Amina J. Mohammed
Olóṣèlú From Wikipedia, the free encyclopedia
Remove ads
Amina Jane Mohammed tí a bí ní 27 June 1971 jé olósèlú omo orílè-èdè Nàìjíríà àti orílè-èdè Britain, òun ígbákejì akowe fun Igbimọ gbogboogbo ti orilẹ-ede Agbaye(United Nations) lowolowo,[2] laarin odun 2015 sí 2016, òun ni lo jé minisita Nàìjíríà fun ètó adugbo.[3]
Remove ads
Ìpìlè àti Èkó rè
A bí Amina Jane Mohammed ni ojo June 27, 1961 ní ìlú Liverpool, England ní orílè-èdè United Kingdom.[4] Baba rè jé Hausa-Fulani, òsì jé Dókítá alabare àwon eranko, Ìyá rè sì jé Noosi omo orílè-èdè United Kingdom. Amina ni omo àkókó larin omo marun.[5]
Mohammed lo ilé-ìwé Primari ní ìpínlè Kaduna, o sì tèsíwájú ní ilé-ìwé Buchan ní orílè-èdè Isle of Man fún ìwé sekondori rè.[3] O tún tèsíwájú ní Henley Management College ni odún 1989. Léyìn tí o parí èkó rè, bàbá rè so pé kí o padà sí Nàìjíríà.[5]
Remove ads
Isé rè
Larin 1981 sí 1991, Mohammed sísé pèlú ilé-isé Archon Nigeria, ilé-isé tí oun yaworan ilé. Ni odun 1991, Mohammed dá ilé-isé Afri-projects Consortium kalè, larin odun 1991 sí odun 2001, oun ni adari àti apase ilé-isé náà.[6]
Àwon Ìtókasí
Wikiwand - on
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Remove ads
