Aretha Franklin
From Wikipedia, the free encyclopedia
Remove ads
Aretha Louise Franklin (March 25, 1942 – August 16, 2018) je akorin, akowe-orin, osere, ateduuru, ati alakitiyan eto araalu ara Amerika.[2] Franklin bere si ni korin lati kekere ninu egbe akorin gospel ni ijo New Bethel Baptist Church ni Detroit, Michigan, nibi ti baba re C. L. Franklin ti je oluso-agutan. Nigba to di omo odun 18, o bere si ni korin to gbode. Awon orin re to gbajumo bi "Respect", "Chain of Fools", "Think", "(You Make Me Feel Like) A Natural Woman", "I Never Loved a Man (The Way I Love You)", ati "I Say a Little Prayer", so di akorin agba lagbaye, eyi to je ki o gbajumo bi Queen of Soul.
![]() |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Remove ads
Àwọn Ìtọ́kasí
Wikiwand - on
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Remove ads