Aymara

From Wikipedia, the free encyclopedia

Aymara
Remove ads

Omo egbé Quechumaran ni Aymara. Quechumaran fúnrarè náà jé omo egbé fún àwon èdè Andea-Equatorial. Àwon tí ó ń so àwon èdè wònyí lé díè ní mílíònù méjì (2.2.million). Púpò nínú àwon tí ó ń so wón wà ní Bolivia (1.8 million) ó dín díè ní mílíònù méjì. Wón tún ń so àwon èdè wònyí ní Peru àti apá kan Argentina. Àkótó Rómáànù ni wón fi ń ko ó sílè. Ní ìgbà kan rí, Aymara jé èdè kan tí ó se pàtàkì ní ààrin gbùngbùn Andes tí wón jé apá kan Énípáyà Inca (Inca Empire)

Quick facts Àpapọ̀ iye oníbùgbé, Regions with significant populations ...

Aymara


Remove ads

Itokasi

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads