Azerbaijan

From Wikipedia, the free encyclopedia

Azerbaijan
Remove ads

Aserbaijan Ní ètò ìkànìyàn 1995, àwọn tí ó ń sọ èdè yìí jẹ́ mílíọ̀nù méjè àbọ̀. Òun ni ó jẹ́ èdè ìjọba fún Aserbaijani níbi tí àwọn ìdá mẹ́ta nínú mẹ́rin àwọn tí ó ń gbé ibẹ̀ ti ń sọ ọ́. Àwọn ìdá mẹ́fà nínú ọgọ́rùn-ún àwọn ènìyàn tí ó ń gbé Rọ́sía ni ó ń sọ èdè yìí. Àwọn èdè bú méjìlà mìíràn tún wà èyí tí Avar àti Armerican wà lára wọn.

Quick Facts Orile ede Aserbaijan Azərbaycan Respublikası, Olùìlú àti ìlú tótóbijùlọ ...
Remove ads

Itokasi

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads