Baku

From Wikipedia, the free encyclopedia

Baku
Remove ads

Baku (Azerbaijani: Bakı), nigba miran bi Baqy, Baky, Baki tabi Bakou, ni oluilu, ilu totobijulo ati ebute totobijulo ni orile-ede Azerbaijan ati ni gbogbo Kaukasu. O wa ni apaguusu ebado Absheron Peninsula, Baku pin si apa meji: isale ilu ati Arin Ilu atijo (21.5 ha). Ojo ori re bere lati igbajoun, olugbe ibe nibere 2009 je egbegberun meji awon eniyan.[2]

Quick Facts Baku Bakı, Orile-ede ...


Remove ads

Àwọn Ìtọ́kasí

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads