Bùrúndì
From Wikipedia, the free encyclopedia
Remove ads
Bùrúndì (pipe /bəˈɹʊndɨ/), lonibise bi Orílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ Bùrúndì (Kirundi: Republika y'u Burundi, [buˈɾundi]; Faransé: République du Burundi, [byˈʁyndi]), je orile-ede ademolesarin ni agbegbe awon Adagun Ninla ni Apailaorun Afrika to ni bode mo Rwanda ni ariwa, Tanzania ni ilaorun ati guusu, ati Orile-ede Olominira Oloselu ile Kongo ni iwoorun. Oluilu re ni Bujumbura. Botilejepe orile-ede na je ademolesarin, opo bode re ni apa guusuiwoorun wa niwaju Adagun Tanganyika.
Awon Twa, Tutsi, ati Hutu ni won ti ungbe ni Burundi latigba ti orile-ede na ti je didasile ni orundun marun seyin. Burundi je jijoba lelori bi ileoba latowo awon Tutsi fun ogorun meji odun. Sugbon latibere orundun ogun Jemani ati Belgium gba ori ibe won si so ibe di ileamusin to ruko re unje Ruanda-Urundi.
Cobalt ati baba ni meji ninu awon ohun alumoni ti Burundi ni. Bakanna Burundi unta kofi ati suga.
Remove ads
Àwọn ìpínlẹ̀ ìjọba
Burundi jẹ́ pípín sí ìgbèríko 18,[5] 117 communes,[6] and 2,638 collines (hills).[7] Provincial governments are structured upon these boundaries. In 2000, the province encompassing Bujumbura was separated into two provinces, Bujumbura Rural and Bujumbura Mairie.[8] The newest province, Rumonge, was created on 26 March 2015 from portions of Bujumbura Rural and Bururi.[9]
![]() |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Remove ads
Itokasi
Wikiwand - on
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Remove ads